Àìsáyà 41:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti gbé ẹnì kan dìde láti àríwá, ó sì máa wá,+Ẹnì kan láti ibi tí oòrùn ti ń yọ*+ tó máa ké pe orúkọ mi. Ó máa tẹ àwọn alákòóso* mọ́lẹ̀ bíi pé amọ̀ ni wọ́n,+Bí amọ̀kòkò tó ń tẹ amọ̀ rírin mọ́lẹ̀.
25 Mo ti gbé ẹnì kan dìde láti àríwá, ó sì máa wá,+Ẹnì kan láti ibi tí oòrùn ti ń yọ*+ tó máa ké pe orúkọ mi. Ó máa tẹ àwọn alákòóso* mọ́lẹ̀ bíi pé amọ̀ ni wọ́n,+Bí amọ̀kòkò tó ń tẹ amọ̀ rírin mọ́lẹ̀.