Àìsáyà 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Bí egbin tí wọ́n ń dọdẹ àti bí agbo ẹran tí kò sí ẹnikẹ́ni tó máa kó wọn jọ,Kálukú máa pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀;Kálukú sì máa sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+
14 Bí egbin tí wọ́n ń dọdẹ àti bí agbo ẹran tí kò sí ẹnikẹ́ni tó máa kó wọn jọ,Kálukú máa pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀;Kálukú sì máa sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+