Jeremáyà 50:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+ Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+
34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+ Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+