Àìsáyà 48:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+ Ìfihàn 18:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo gbọ́ ohùn míì láti ọ̀run, ó sọ pé: “Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀, ẹ̀yin èèyàn mi,+ tí ẹ kò bá fẹ́ pín nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ kò bá sì fẹ́ gbà lára àwọn ìyọnu rẹ̀.+
20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+
4 Mo gbọ́ ohùn míì láti ọ̀run, ó sọ pé: “Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀, ẹ̀yin èèyàn mi,+ tí ẹ kò bá fẹ́ pín nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, tí ẹ kò bá sì fẹ́ gbà lára àwọn ìyọnu rẹ̀.+