49 “Jèhófà máa gbé orílẹ̀-èdè kan tó wà lọ́nà jíjìn+ dìde sí ọ, láti ìkángun ayé; ó máa kì ọ́ mọ́lẹ̀ bí ẹyẹ idì+ ṣe ń ṣe, orílẹ̀-èdè tí o ò ní gbọ́+ èdè rẹ̀, 50 orílẹ̀-èdè tí ojú rẹ̀ le gan-an, tí kò ní wo ojú arúgbó, tí kò sì ní ṣojúure sí àwọn ọmọdé.+