2 Àwọn Ọba 21:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹni ọdún méjìlélógún (22) ni Ámọ́nì+ nígbà tó jọba, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Méṣúlémétì ọmọ Hárúsì láti Jótíbà. 20 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà bí Mánásè bàbá rẹ̀ ti ṣe.+
19 Ẹni ọdún méjìlélógún (22) ni Ámọ́nì+ nígbà tó jọba, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Méṣúlémétì ọmọ Hárúsì láti Jótíbà. 20 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà bí Mánásè bàbá rẹ̀ ti ṣe.+