Léfítíkù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run. Àìsáyà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ilẹ̀ yín ti di ahoro. Wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín. Àwọn àjèjì jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.+ Ó dà bí ilẹ̀ tó di ahoro tí àwọn àjèjì gbà.+ Àìsáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ni mo bá sọ pé: “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” Ó dáhùn pé: “Títí àwọn ìlú náà fi máa fọ́ túútúú, tí kò sì ní sẹ́ni tó ń gbé ibẹ̀,Tí kò ní sẹ́nì kankan nínú àwọn ilé,Títí ilẹ̀ náà fi máa pa run, tó sì máa di ahoro;+
33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.
7 Ilẹ̀ yín ti di ahoro. Wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín. Àwọn àjèjì jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.+ Ó dà bí ilẹ̀ tó di ahoro tí àwọn àjèjì gbà.+
11 Ni mo bá sọ pé: “Títí dìgbà wo, Jèhófà?” Ó dáhùn pé: “Títí àwọn ìlú náà fi máa fọ́ túútúú, tí kò sì ní sẹ́ni tó ń gbé ibẹ̀,Tí kò ní sẹ́nì kankan nínú àwọn ilé,Títí ilẹ̀ náà fi máa pa run, tó sì máa di ahoro;+