Àìsáyà 29:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, èmi ni Ẹni tó tún máa ṣe àwọn ohun àgbàyanu sí àwọn èèyàn yìí,+Ohun àgbàyanu kan tẹ̀ lé òmíràn;Ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n wọn máa ṣègbé,Òye àwọn olóye wọn sì máa fara pa mọ́.”+
14 Torí náà, èmi ni Ẹni tó tún máa ṣe àwọn ohun àgbàyanu sí àwọn èèyàn yìí,+Ohun àgbàyanu kan tẹ̀ lé òmíràn;Ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n wọn máa ṣègbé,Òye àwọn olóye wọn sì máa fara pa mọ́.”+