Àìsáyà 41:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí náà, oníṣẹ́ ọnà ń fún oníṣẹ́ irin+ lókun;Ẹni tó ń fi òòlù irin* lu nǹkan di pẹlẹbẹŃ fún ẹni tó ń fi òòlù lu nǹkan lórí irin lókun. Ó ń sọ nípa ohun tí wọ́n jó pọ̀ pé: “Ó dáa.” Wọ́n wá fi ìṣó kàn án, kó má bàa ṣubú.
7 Torí náà, oníṣẹ́ ọnà ń fún oníṣẹ́ irin+ lókun;Ẹni tó ń fi òòlù irin* lu nǹkan di pẹlẹbẹŃ fún ẹni tó ń fi òòlù lu nǹkan lórí irin lókun. Ó ń sọ nípa ohun tí wọ́n jó pọ̀ pé: “Ó dáa.” Wọ́n wá fi ìṣó kàn án, kó má bàa ṣubú.