Jeremáyà 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́,+Àwọn àlùfáà sì ń fi àṣẹ wọn tẹ àwọn èèyàn lórí ba. Àwọn èèyàn mi sì fẹ́ ẹ bẹ́ẹ̀.+ Àmọ́, kí lẹ máa ṣe nígbà tí òpin bá dé?”
31 Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́,+Àwọn àlùfáà sì ń fi àṣẹ wọn tẹ àwọn èèyàn lórí ba. Àwọn èèyàn mi sì fẹ́ ẹ bẹ́ẹ̀.+ Àmọ́, kí lẹ máa ṣe nígbà tí òpin bá dé?”