Àìsáyà 30:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’ Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+ Ọ̀rọ̀ dídùn* ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+ Jòhánù 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ohun tí a máa gbé ìdájọ́ kà nìyí: pé ìmọ́lẹ̀ ti wá sí ayé,+ àmọ́ àwọn èèyàn nífẹ̀ẹ́ òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, torí pé oníṣẹ́ ibi ni wọ́n.
10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’ Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+ Ọ̀rọ̀ dídùn* ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+
19 Ohun tí a máa gbé ìdájọ́ kà nìyí: pé ìmọ́lẹ̀ ti wá sí ayé,+ àmọ́ àwọn èèyàn nífẹ̀ẹ́ òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, torí pé oníṣẹ́ ibi ni wọ́n.