Ẹ́kísódù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+ Àìsáyà 47:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+
5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+
6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+