Jeremáyà 9:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá tú wọn ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn pẹ̀lú àwọn baba wọn kò mọ̀,+ màá sì rán idà sí wọn títí màá fi pa wọ́n run.’+ Ìsíkíẹ́lì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àjàkálẹ̀ àrùn* tàbí ìyàn máa pa ìdá mẹ́ta lára yín. Wọ́n á sì fi idà pa ìdá mẹ́ta míì láyìíká yín.+ Màá fọ́n ìdá mẹ́ta yòókù káàkiri,* màá sì fa idà yọ láti fi lé wọn.+
16 Màá tú wọn ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí àwọn pẹ̀lú àwọn baba wọn kò mọ̀,+ màá sì rán idà sí wọn títí màá fi pa wọ́n run.’+
12 Àjàkálẹ̀ àrùn* tàbí ìyàn máa pa ìdá mẹ́ta lára yín. Wọ́n á sì fi idà pa ìdá mẹ́ta míì láyìíká yín.+ Màá fọ́n ìdá mẹ́ta yòókù káàkiri,* màá sì fa idà yọ láti fi lé wọn.+