-
2 Àwọn Ọba 16:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí náà, Áhásì rán àwọn òjíṣẹ́ sí Tigilati-pílésà+ ọba Ásíríà, ó ní: “Ìránṣẹ́ rẹ ni mí, ọmọ rẹ sì ni mo jẹ́. Wá gbà mí lọ́wọ́ ọba Síríà àti lọ́wọ́ ọba Ísírẹ́lì tí wọ́n ń gbéjà kò mí.”
-
-
Hósíà 5:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nígbà tí Éfúrémù rí i pé òun ń ṣàìsàn, tí Júdà sì rí i pé egbò wà lára òun,
Éfúrémù lọ sí Ásíríà,+ ó sì ránṣẹ́ sí ọba ńlá.
Ṣùgbọ́n kò lè mú un lára dá,
Kò sì lè wo egbò rẹ̀ sàn.
-