18 Wọ́n fi ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sin àwọn òpó òrìṣà* àti àwọn òrìṣà, tó fi di pé Ọlọ́run bínú* sí Júdà àti Jerúsálẹ́mù nítorí pé wọ́n ti jẹ̀bi.
3 Ó tún àwọn ibi gíga kọ́, èyí tí Hẹsikáyà bàbá rẹ̀ ti wó lulẹ̀,+ ó mọ àwọn pẹpẹ fún Báálì, ó sì ṣe àwọn òpó òrìṣà.* Ó forí balẹ̀ fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run, ó sì ń sìn wọ́n.+