ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 5:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àwọn tó ń sọ pé: “Kó jẹ́ kí iṣẹ́ Rẹ̀ yára kánkán;

      Kó tètè dé, ká lè rí i.

      Kí ohun tí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ní lọ́kàn* ṣẹ,

      Ká lè mọ̀ ọ́n!”+

  • 2 Pétérù 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 wọ́n á máa sọ pé: “Ṣebí ó ṣèlérí pé òun máa wà níhìn-ín, òun wá dà?+ Ó ṣe tán, bí nǹkan ṣe rí gẹ́lẹ́ láti ọjọ́ tí àwọn baba ńlá wa ti sùn nínú ikú, bẹ́ẹ̀ náà ló rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀dá.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́