ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 17:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Wò ó! Àwọn kan ń sọ fún mi pé:

      “Ọ̀rọ̀ Jèhófà dà?+

      Jọ̀wọ́, jẹ́ kó wá!”

  • Mátíù 24:48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 “Àmọ́ tí ẹrú burúkú yẹn bá lọ sọ nínú ọkàn rẹ̀ pé, ‘Ọ̀gá mi ń pẹ́,’+

  • Lúùkù 12:45
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Àmọ́ tí ẹrú yẹn bá lọ sọ nínú ọkàn rẹ̀ pé, ‘Ọ̀gá mi ò tètè dé,’ tó wá bẹ̀rẹ̀ sí í lu àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, tó ń jẹ, tó ń mu, tó sì mutí yó,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́