Jeremáyà 22:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí bí ẹ bá ṣe ohun tí mo sọ yìí tọkàntọkàn, nígbà náà àwọn ọba tó ń jókòó lórí ìtẹ́ Dáfídì+ máa gba àwọn ẹnubodè ilé yìí wọlé, àwọn àti àwọn ìránṣẹ́ wọn pẹ̀lú àwọn èèyàn wọn á gun kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn ẹṣin.”’+
4 Torí bí ẹ bá ṣe ohun tí mo sọ yìí tọkàntọkàn, nígbà náà àwọn ọba tó ń jókòó lórí ìtẹ́ Dáfídì+ máa gba àwọn ẹnubodè ilé yìí wọlé, àwọn àti àwọn ìránṣẹ́ wọn pẹ̀lú àwọn èèyàn wọn á gun kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn ẹṣin.”’+