2 Àwọn Ọba 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ọdún kẹsàn-án ìjọba Sedekáyà, ní oṣù kẹwàá, ní ọjọ́ kẹwàá oṣù náà, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì dé pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ láti gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+ Ó dó tì í, ó mọ òkìtì yí i ká,+ Jeremáyà 32:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá fi ìlú yìí lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà àti Nebukadinésárì* ọba Bábílónì, á sì gbà á.+ Jeremáyà 39:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ní ọdún kẹsàn-án Sedekáyà ọba Júdà, ní oṣù kẹwàá, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì àti gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ wá sí Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì dó tì í.+
25 Ní ọdún kẹsàn-án ìjọba Sedekáyà, ní oṣù kẹwàá, ní ọjọ́ kẹwàá oṣù náà, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì dé pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ láti gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+ Ó dó tì í, ó mọ òkìtì yí i ká,+
28 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá fi ìlú yìí lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà àti Nebukadinésárì* ọba Bábílónì, á sì gbà á.+
39 Ní ọdún kẹsàn-án Sedekáyà ọba Júdà, ní oṣù kẹwàá, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì àti gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ wá sí Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì dó tì í.+