-
Diutarónómì 30:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa mú ọ wá sí ilẹ̀ tí àwọn bàbá rẹ gbà, ó sì máa di tìẹ; á mú kí nǹkan máa lọ dáadáa fún ọ, á sì mú kí o pọ̀ ju àwọn bàbá+ rẹ.
-
-
Sekaráyà 10:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 ‘Màá súfèé sí wọn, màá sì kó wọn jọ;
Torí màá rà wọ́n pa dà,+ wọ́n á sì pọ̀ sí i,
Wọ́n á sì máa pọ̀ sí i.
-