-
2 Kíróníkà 28:20-22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Níkẹyìn, Tiliga-pílínésà+ ọba Ásíríà wá gbéjà kò ó, ó sì kó ìdààmú bá a+ dípò kó fún un lókun. 21 Áhásì ti kó àwọn nǹkan tó wà ní ilé Jèhófà àti ilé* ọba+ àti ilé àwọn ìjòyè, ó sì fi ṣe ẹ̀bùn fún ọba Ásíríà; àmọ́ kò ṣe é láǹfààní kankan. 22 Nígbà tí Ọba Áhásì wà nínú ìdààmú, ńṣe ló túbọ̀ ń hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà.
-