Jeremáyà 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Àmọ́ ní ti ọ̀pọ̀tọ́ tó ti bà jẹ́ débi pé kò ṣeé jẹ,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Bákan náà ni màá ṣe sí Sedekáyà+ ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù tó wà ní ilẹ̀ yìí àti àwọn tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
8 “‘Àmọ́ ní ti ọ̀pọ̀tọ́ tó ti bà jẹ́ débi pé kò ṣeé jẹ,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Bákan náà ni màá ṣe sí Sedekáyà+ ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù tó wà ní ilẹ̀ yìí àti àwọn tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì.+