Jeremáyà 29:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wò ó, màá rán idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn*+ sí wọn, màá sì ṣe wọ́n bí ọ̀pọ̀tọ́ jíjẹrà* tó ti bà jẹ́ débi pé kò ṣeé jẹ.”’+
17 ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wò ó, màá rán idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn*+ sí wọn, màá sì ṣe wọ́n bí ọ̀pọ̀tọ́ jíjẹrà* tó ti bà jẹ́ débi pé kò ṣeé jẹ.”’+