-
Jeremáyà 24:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ọ̀pọ̀tọ́ inú apẹ̀rẹ̀ àkọ́kọ́ dára gan-an, ó dà bí àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́, àmọ́ ọ̀pọ̀tọ́ inú apẹ̀rẹ̀ kejì ti bà jẹ́ gan-an débi pé kò ṣeé jẹ.
-