Jeremáyà 24:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Màá sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù àti àjálù lójú gbogbo ìjọba ayé,+ màá jẹ́ kí wọ́n di ẹni ẹ̀gàn àti ẹni àfipòwe, ẹni ẹ̀sín àti ẹni ègún + ní gbogbo ibi tí màá fọ́n wọn ká sí.+
9 Màá sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù àti àjálù lójú gbogbo ìjọba ayé,+ màá jẹ́ kí wọ́n di ẹni ẹ̀gàn àti ẹni àfipòwe, ẹni ẹ̀sín àti ẹni ègún + ní gbogbo ibi tí màá fọ́n wọn ká sí.+