17 “Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Ẹ kò ṣègbọràn sí mi, torí pé kálukú yín kò kéde òmìnira fún arákùnrin rẹ̀ àti ọmọnìkejì rẹ̀.+ Òmìnira tí màá kéde fún yín nìyí, ni Jèhófà wí, idà, àjàkálẹ̀ àrùn àti ìyàn ni yóò pa yín,+ màá sì sọ yín di ohun àríbẹ̀rù lójú gbogbo ìjọba ayé.+