Jeremáyà 2:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Lásán ni mo lu àwọn ọmọ yín.+ Wọn kò ní gba ìbáwí;+Idà yín ti pa àwọn wòlíì yín,+Bíi kìnnìún tó ń wá ẹran kiri.
30 Lásán ni mo lu àwọn ọmọ yín.+ Wọn kò ní gba ìbáwí;+Idà yín ti pa àwọn wòlíì yín,+Bíi kìnnìún tó ń wá ẹran kiri.