-
Jeremáyà 38:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ṣùgbọ́n Jeremáyà sọ pé: “Wọn kò ní fà ọ́ lé wọn lọ́wọ́. Jọ̀wọ́, ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà lórí ohun tí mò ń sọ fún ọ, nǹkan á lọ dáadáa fún ọ, wàá* sì máa wà láàyè.
-