-
Jeremáyà 27:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “‘Nítorí mi ò rán wọn,’ ni Jèhófà wí, ‘ṣùgbọ́n wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké ní orúkọ mi, kí n lè fọ́n yín ká, kí ẹ sì ṣègbé, ẹ̀yin àti àwọn wòlíì tó ń sọ tẹ́lẹ̀ fún yín.’”+
-