-
Jeremáyà 29:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wò ó, màá fìyà jẹ Ṣemáyà ará Néhélámù àti àtọmọdọ́mọ rẹ̀. Kò ní sí ọkùnrin kankan tó jẹ́ tirẹ̀ tó máa yè bọ́ lára àwọn èèyàn yìí, kò sì ní rí ohun rere tí màá ṣe fún àwọn èèyàn mi,’ ni Jèhófà wí, ‘nítorí ó ti mú kí wọ́n dìtẹ̀ sí Jèhófà.’”’”
-