-
Jeremáyà 51:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ilẹ̀ ayé á mì tìtì, jìnnìjìnnì á sì bá a,
Nítorí pé èrò Jèhófà sí Bábílónì máa ṣẹ
Láti sọ ilẹ̀ Bábílónì di ohun àríbẹ̀rù, tí ẹnì kánkán kò ní gbé ibẹ̀.+
-
-
Míkà 5:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ọwọ́ yín máa lékè àwọn elénìní yín,
Gbogbo ọ̀tá yín sì máa pa run.”
-