Diutarónómì 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jèhófà máa mú kí o ya wèrè, kí o fọ́jú,+ kí nǹkan sì dà rú fún ọ.* Sefanáyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá fa wàhálà bá aráyé,Wọ́n á sì máa rìn bí afọ́jú,+Nítorí pé wọ́n ti ṣẹ Jèhófà.+ A ó tú ẹ̀jẹ̀ wọn jáde bí erukuÀti ẹran ara* wọn bí ìgbẹ́.+
17 Màá fa wàhálà bá aráyé,Wọ́n á sì máa rìn bí afọ́jú,+Nítorí pé wọ́n ti ṣẹ Jèhófà.+ A ó tú ẹ̀jẹ̀ wọn jáde bí erukuÀti ẹran ara* wọn bí ìgbẹ́.+