Àìsáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+ Jeremáyà 2:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Kódà, ẹ̀jẹ̀ àwọn* aláìní tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ ti ta sí ọ láṣọ,+Kì í ṣe torí pé wọ́n ń fọ́lé ni o fi pa wọ́n;Síbẹ̀, mo ṣì rí ẹ̀jẹ̀ wọn lára gbogbo aṣọ rẹ.+
15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+
34 Kódà, ẹ̀jẹ̀ àwọn* aláìní tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ ti ta sí ọ láṣọ,+Kì í ṣe torí pé wọ́n ń fọ́lé ni o fi pa wọ́n;Síbẹ̀, mo ṣì rí ẹ̀jẹ̀ wọn lára gbogbo aṣọ rẹ.+