Diutarónómì 28:65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Ọkàn rẹ ò ní balẹ̀ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè+ yẹn, àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ ò sì ní rí ibi ìsinmi. Dípò ìyẹn, Jèhófà máa mú kí o kó ọkàn sókè,+ ojú rẹ á di bàìbàì, ìrẹ̀wẹ̀sì*+ á sì bá ọ níbẹ̀.
65 Ọkàn rẹ ò ní balẹ̀ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè+ yẹn, àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ ò sì ní rí ibi ìsinmi. Dípò ìyẹn, Jèhófà máa mú kí o kó ọkàn sókè,+ ojú rẹ á di bàìbàì, ìrẹ̀wẹ̀sì*+ á sì bá ọ níbẹ̀.