Ìfihàn 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Áńgẹ́lì náà ti dòjé rẹ̀ bọ ayé, ó kó àjàrà ayé jọ, ó sì jù ú síbi tí ó tóbi tí a ti ń fún wáìnì ti ìbínú Ọlọ́run.+ Ìfihàn 19:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Idà tó mú, tó sì gùn jáde láti ẹnu rẹ̀,+ kó lè fi pa àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa fi ọ̀pá irin ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn.+ Bákan náà, ó ń tẹ ìbínú àti ìrunú Ọlọ́run Olódùmarè níbi tí a ti ń fún wáìnì.+
19 Áńgẹ́lì náà ti dòjé rẹ̀ bọ ayé, ó kó àjàrà ayé jọ, ó sì jù ú síbi tí ó tóbi tí a ti ń fún wáìnì ti ìbínú Ọlọ́run.+
15 Idà tó mú, tó sì gùn jáde láti ẹnu rẹ̀,+ kó lè fi pa àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa fi ọ̀pá irin ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn.+ Bákan náà, ó ń tẹ ìbínú àti ìrunú Ọlọ́run Olódùmarè níbi tí a ti ń fún wáìnì.+