-
Diutarónómì 28:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Wọ́n á fún àwọn èèyàn míì+ ní àwọn ọmọkùnrin àtàwọn ọmọbìnrin rẹ níṣojú rẹ, àárò wọn á máa sọ ẹ́ nígbà gbogbo, àmọ́ o ò ní rí nǹkan kan ṣe sí i.
-