1 Kíróníkà 28:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìgbà náà ni Ọba Dáfídì dìde dúró, ó sì sọ pé: “Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin arákùnrin mi àti ẹ̀yin èèyàn mi. Ó jẹ́ ìfẹ́ ọkàn mi láti kọ́ ilé tó máa jẹ́ ibi ìsinmi fún àpótí májẹ̀mú Jèhófà, tí á sì jẹ́ àpótí ìtìsẹ̀ fún Ọlọ́run wa,+ mo sì ti ṣètò sílẹ̀ láti kọ́ ọ.+ Sáàmù 132:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ jẹ́ ká wá sínú ibùgbé rẹ̀;*+Ká forí balẹ̀ níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀.+ Àìsáyà 60:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+
2 Ìgbà náà ni Ọba Dáfídì dìde dúró, ó sì sọ pé: “Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin arákùnrin mi àti ẹ̀yin èèyàn mi. Ó jẹ́ ìfẹ́ ọkàn mi láti kọ́ ilé tó máa jẹ́ ibi ìsinmi fún àpótí májẹ̀mú Jèhófà, tí á sì jẹ́ àpótí ìtìsẹ̀ fún Ọlọ́run wa,+ mo sì ti ṣètò sílẹ̀ láti kọ́ ọ.+
13 Ọ̀dọ̀ rẹ ni ògo Lẹ́bánónì máa wá,+Igi júnípà, igi áàṣì àti igi sípírẹ́sì lẹ́ẹ̀kan náà,+Láti ṣe ibi mímọ́ mi lọ́ṣọ̀ọ́;Màá ṣe ibi tí ẹsẹ̀ mi wà lógo.+