Jeremáyà 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+ Ìsíkíẹ́lì 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wọ́n ti wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ jìnnìjìnnì sì bá wọn.* Ojú á ti gbogbo wọn, orí gbogbo wọn á sì pá.*+
26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+