ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 56:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Màá tún mú wọn wá sí òkè mímọ́ mi,+

      Màá sì mú kí wọ́n máa yọ̀ nínú ilé àdúrà mi.

      Màá tẹ́wọ́ gba odindi ẹbọ sísun wọn àtàwọn ẹbọ wọn lórí pẹpẹ mi.

      Torí a ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà fún gbogbo èèyàn.”+

  • Ìsíkíẹ́lì 20:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 “‘Torí ní òkè mímọ́ mi, ní òkè gíga Ísírẹ́lì,+ ni gbogbo ilé Ísírẹ́lì yóò ti sìn mí ní ilẹ̀ náà, gbogbo wọn pátá,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.+ ‘Inú mi yóò dùn sí wọn níbẹ̀, èmi yóò sì béèrè ọrẹ yín àti àwọn àkọ́so ẹ̀bùn yín, gbogbo ohun mímọ́ yín.+

  • Míkà 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́,*

      Òkè ilé Jèhófà+

      Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,

      A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,

      Àwọn èèyàn á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́