Ìsíkíẹ́lì 39:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Ní tìrẹ, ọmọ èèyàn, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí Gọ́ọ̀gù,+ kí o sì sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò bá ọ jà, Gọ́ọ̀gù, ìwọ olórí ìjòyè* Méṣékì àti Túbálì.+
39 “Ní tìrẹ, ọmọ èèyàn, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí Gọ́ọ̀gù,+ kí o sì sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò bá ọ jà, Gọ́ọ̀gù, ìwọ olórí ìjòyè* Méṣékì àti Túbálì.+