3 Ibi àbáwọlé*+ tó wà níwájú tẹ́ńpìlì* náà jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn,* ó sì bá fífẹ̀ ilé náà mu.* Ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ló fi yọ síta lára iwájú ilé náà.
4 Ibi àbáwọlé* tó wà níwájú jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ó bá fífẹ̀ ilé náà mu,* gíga rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́; * ó wá fi ògidì wúrà bò ó nínú.+