-
Ìsíkíẹ́lì 41:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ilé tó wà ní ìwọ̀ oòrùn tó dojú kọ àyè fífẹ̀ náà jẹ́ àádọ́rin (70) ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀, gígùn rẹ̀ sì jẹ́ àádọ́rùn-ún (90) ìgbọ̀nwọ́; ìnípọn ògiri ilé náà yí ká jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún.
-