Ìsíkíẹ́lì 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Lẹ́yìn náà, ó mú mi wá sí àgbàlá ìta ní apá àríwá.+ Ó mú mi wá sí ilé tó ní àwọn yàrá ìjẹun tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ àyè fífẹ̀ náà,+ ó wà ní àríwá ilé tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.+
42 Lẹ́yìn náà, ó mú mi wá sí àgbàlá ìta ní apá àríwá.+ Ó mú mi wá sí ilé tó ní àwọn yàrá ìjẹun tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ àyè fífẹ̀ náà,+ ó wà ní àríwá ilé tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.+