-
Ìsíkíẹ́lì 1:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Nígbà tí mo gbọ́ ìró ìyẹ́ wọn, ó dà bí ìró omi púpọ̀ tó ń rọ́ jáde, bí ìró láti ọ̀dọ̀ Olódùmarè.+ Tí wọ́n bá gbéra, ìró wọn dà bíi ti àwọn ọmọ ogun. Tí wọ́n bá dúró, wọ́n á ká ìyẹ́ wọn sílẹ̀.
-