-
Ìfihàn 14:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Mo gbọ́ ìró kan tó dún láti ọ̀run bí ìró omi púpọ̀ àti bí ìró ààrá tó rinlẹ̀ gan-an; ìró tí mo gbọ́ náà sì dà bíi ti àwọn akọrin tí wọ́n ń ta háàpù sí orin tí wọ́n ń kọ.
-