-
Jóṣúà 21:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì wá lọ bá àlùfáà Élíásárì+ àti Jóṣúà ọmọ Núnì pẹ̀lú àwọn olórí agbo ilé bàbá nínú ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, 2 wọ́n sì sọ fún wọn ní Ṣílò+ ní ilẹ̀ Kénáánì pé: “Jèhófà pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè pé kí wọ́n fún wa ní àwọn ìlú tí a máa gbé, pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ẹran ọ̀sìn wa.”+
-