-
Nọ́ńbà 35:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú tí wọ́n á máa gbé látinú ogún tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa gbà,+ kí wọ́n sì fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ibi ìjẹko tó yí àwọn ìlú+ náà ká. 3 Wọ́n á máa gbé àwọn ìlú náà, ibi ìjẹko náà á sì wà fún àwọn ẹran ọ̀sìn wọn, àwọn ẹrù wọn àti gbogbo ẹran wọn yòókù. 4 Kí ibi ìjẹko tó yí àwọn ìlú tí ẹ máa fún àwọn ọmọ Léfì ká jẹ́ ẹgbẹ̀rún (1,000) ìgbọ̀nwọ́* láti ògiri ìlú náà yí ká.
-