-
Ìsíkíẹ́lì 48:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Ohun tó bá ṣẹ́ kù lẹ́gbẹ̀ẹ́ méjèèjì ilẹ̀ mímọ́ náà àti ohun ìní ìlú náà yóò jẹ́ ti ìjòyè.+ Yóò wà lẹ́bàá àwọn ààlà tó wà ní apá ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ mímọ́ náà, tí gígùn wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́. Yóò dọ́gba pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ tí wọ́n jọ pààlà, yóò sì jẹ́ ti ìjòyè. Àárín rẹ̀ ni ilẹ̀ mímọ́ náà àti ibi mímọ́ tẹ́ńpìlì náà yóò wà.
-