-
Ìsíkíẹ́lì 45:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “‘Ní ti ìjòyè, ilẹ̀ rẹ̀ yóò wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ méjèèjì ilẹ̀ mímọ́ náà àti lẹ́gbẹ̀ẹ́ ilẹ̀ tó jẹ́ ti ìlú. Yóò wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ilẹ̀ mímọ́ náà àti ilẹ̀ tó jẹ́ ti ìlú náà. Apá ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn ló máa wà. Gígùn rẹ̀ láti ààlà ìwọ̀ oòrùn dé ààlà ìlà oòrùn yóò dọ́gba pẹ̀lú ọ̀kan nínú àwọn ilẹ̀ tí ẹ̀yà kan ní.+
-