ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 16:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Kí gbogbo ọkùnrin rẹ máa fara hàn níwájú Jèhófà Ọlọ́run lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún ní ibi tó bá yàn: ní Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀+ àti Àjọyọ̀ Àtíbàbà,+ kí ẹnì kankan nínú wọn má sì wá síwájú Jèhófà lọ́wọ́ òfo.

  • 2 Kíróníkà 8:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Lẹ́yìn náà, Sólómọ́nì rú àwọn ẹbọ sísun+ sí Jèhófà lórí pẹpẹ+ Jèhófà tí ó mọ síwájú ibi àbáwọlé.*+ 13 Ó ń ṣe ohun tí wọ́n máa ń ṣe lójoojúmọ́, ó sì ń mú ọrẹ wá gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Mósè pa ní ti àwọn Sábáàtì,+ àwọn òṣùpá tuntun+ àti àwọn àjọyọ̀ tó máa ń wáyé nígbà mẹ́ta lọ́dún,+ ìyẹn Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀+ àti Àjọyọ̀ Àtíbàbà.+

  • 2 Kíróníkà 31:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ọba fi apá kan lára ẹrù rẹ̀ sílẹ̀ fún àwọn ẹbọ sísun,+ ìyẹn àwọn ẹbọ òwúrọ̀ àti ti ìrọ̀lẹ́,+ títí kan àwọn ẹbọ sísun fún àwọn Sábáàtì,+ àwọn òṣùpá tuntun+ àti àwọn àjọyọ̀,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́